Ìfihàn 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mànàmáná+ àti ohùn àti ààrá+ sì ń jáde wá láti ibi ìtẹ́ náà; fìtílà méje tó ní iná ń jó níwájú ìtẹ́ náà, àwọn yìí sì túmọ̀ sí ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run.+
5 Mànàmáná+ àti ohùn àti ààrá+ sì ń jáde wá láti ibi ìtẹ́ náà; fìtílà méje tó ní iná ń jó níwájú ìtẹ́ náà, àwọn yìí sì túmọ̀ sí ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run.+