Ìfihàn 22:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Aláyọ̀ ni àwọn tó fọ aṣọ wọn,+ kí wọ́n lè ní àṣẹ láti lọ síbi àwọn igi ìyè,+ kí wọ́n sì lè gba ẹnubodè wọnú ìlú náà.+
14 Aláyọ̀ ni àwọn tó fọ aṣọ wọn,+ kí wọ́n lè ní àṣẹ láti lọ síbi àwọn igi ìyè,+ kí wọ́n sì lè gba ẹnubodè wọnú ìlú náà.+