Títù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 èyí tó dá lórí ìrètí ìyè àìnípẹ̀kun+ tí Ọlọ́run, ẹni tí kò lè parọ́,+ ti ṣèlérí tipẹ́tipẹ́;