Ìfihàn 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Mo rí àmì míì ní ọ̀run, ó kàmàmà, ó sì yani lẹ́nu, áńgẹ́lì méje+ tí wọ́n ní ìyọnu méje. Àwọn yìí ló kẹ́yìn, torí a máa tipasẹ̀ wọn mú ìbínú Ọlọ́run wá sí òpin.+
15 Mo rí àmì míì ní ọ̀run, ó kàmàmà, ó sì yani lẹ́nu, áńgẹ́lì méje+ tí wọ́n ní ìyọnu méje. Àwọn yìí ló kẹ́yìn, torí a máa tipasẹ̀ wọn mú ìbínú Ọlọ́run wá sí òpin.+