Ìfihàn 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí ẹni tó bá ní etí gbọ́ ohun tí ẹ̀mí ń sọ fún àwọn ìjọ:+ Ẹni tó bá ṣẹ́gun+ ni màá jẹ́ kó jẹ nínú igi ìyè+ tó wà nínú párádísè Ọlọ́run.’
7 Kí ẹni tó bá ní etí gbọ́ ohun tí ẹ̀mí ń sọ fún àwọn ìjọ:+ Ẹni tó bá ṣẹ́gun+ ni màá jẹ́ kó jẹ nínú igi ìyè+ tó wà nínú párádísè Ọlọ́run.’