Ìfihàn 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Mò ń bọ̀ kíákíá.+ Di ohun tí o ní mú ṣinṣin, kí ẹnì kankan má bàa gba adé rẹ.+ Ìfihàn 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wò ó! mò ń bọ̀ kíákíá.+ Aláyọ̀ ni ẹnikẹ́ni tó bá ń pa àwọn ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ àkájọ ìwé yìí mọ́.”+