Lúùkù 12:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Mò ń sọ fún yín pé, gbogbo ẹni tó bá fi hàn pé òun mọ̀ mí níwájú àwọn èèyàn,+ Ọmọ èèyàn náà máa fi hàn pé òun mọ̀ ọ́n níwájú àwọn áńgẹ́lì Ọlọ́run.+ 1 Jòhánù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹnikẹ́ni tó bá sẹ́ Ọmọ kò ní Baba.+ Ẹnikẹ́ni tó bá sọ pé òun mọ Ọmọ+ ní Baba pẹ̀lú.+
8 “Mò ń sọ fún yín pé, gbogbo ẹni tó bá fi hàn pé òun mọ̀ mí níwájú àwọn èèyàn,+ Ọmọ èèyàn náà máa fi hàn pé òun mọ̀ ọ́n níwájú àwọn áńgẹ́lì Ọlọ́run.+