Ìfihàn 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 ẹnì kan tó dà bí ọmọ èèyàn+ wà láàárín àwọn ọ̀pá fìtílà náà, ó wọ aṣọ tó balẹ̀ dé ọrùn ẹsẹ̀, ó de ọ̀já wúrà mọ́ àyà rẹ̀. Ìfihàn 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìràwọ̀ méje wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀,+ idà olójú méjì,+ tó mú, tó sì gùn yọ jáde láti ẹnu rẹ̀, ìrísí ojú rẹ̀ sì dà bí oòrùn tó ń mú ganrín-ganrín.+
13 ẹnì kan tó dà bí ọmọ èèyàn+ wà láàárín àwọn ọ̀pá fìtílà náà, ó wọ aṣọ tó balẹ̀ dé ọrùn ẹsẹ̀, ó de ọ̀já wúrà mọ́ àyà rẹ̀.
16 Ìràwọ̀ méje wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀,+ idà olójú méjì,+ tó mú, tó sì gùn yọ jáde láti ẹnu rẹ̀, ìrísí ojú rẹ̀ sì dà bí oòrùn tó ń mú ganrín-ganrín.+