Ìṣe 16:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Obìnrin kan tó ń jẹ́ Lìdíà, tó ń ta aṣọ aláwọ̀ pọ́pù, tó wá láti ìlú Tíátírà,+ tó sì jẹ́ olùjọsìn Ọlọ́run, ń fetí sílẹ̀, Jèhófà* sì ṣí ọkàn rẹ̀ sílẹ̀ láti fiyè sí ohun tí Pọ́ọ̀lù ń sọ.
14 Obìnrin kan tó ń jẹ́ Lìdíà, tó ń ta aṣọ aláwọ̀ pọ́pù, tó wá láti ìlú Tíátírà,+ tó sì jẹ́ olùjọsìn Ọlọ́run, ń fetí sílẹ̀, Jèhófà* sì ṣí ọkàn rẹ̀ sílẹ̀ láti fiyè sí ohun tí Pọ́ọ̀lù ń sọ.