Kólósè 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 òun sì ni orí fún ara, ìyẹn ìjọ.+ Òun ni ìbẹ̀rẹ̀, àkọ́bí nínú àwọn òkú,+ kí ó lè di ẹni àkọ́kọ́ nínú ohun gbogbo;
18 òun sì ni orí fún ara, ìyẹn ìjọ.+ Òun ni ìbẹ̀rẹ̀, àkọ́bí nínú àwọn òkú,+ kí ó lè di ẹni àkọ́kọ́ nínú ohun gbogbo;