ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 64
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Àdúrà ìrònúpìwàdà ń bá a lọ (1-12)

        • Jèhófà, “Ẹni tó mọ wá” (8)

Àìsáyà 64:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 363-364

Àìsáyà 64:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 363-364

Àìsáyà 64:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:10
  • +Hab 3:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 364

Àìsáyà 64:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ń fi sùúrù dúró dè é.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 130:6-8; Ais 25:9; Mik 7:7; 1Kọ 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 364

Àìsáyà 64:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sef 2:3; Iṣe 10:34, 35
  • +Ais 1:21; 63:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 364

Àìsáyà 64:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 12:2; 15:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 365

Àìsáyà 64:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “yọ́.”

  • *

    Ní Héb., “látọwọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:17; Ais 57:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 366-368

Àìsáyà 64:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹni tó dá wa; Amọ̀kòkò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 63:16
  • +Ais 29:16; 45:9; Jer 18:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2016, ojú ìwé 6-10

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2013, ojú ìwé 20-21

    6/15/2013, ojú ìwé 25

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 368

Àìsáyà 64:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 74:1; 79:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 368

Àìsáyà 64:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 79:1; Ida 1:4; 5:18; Mik 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 368-369

Àìsáyà 64:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Tẹ́ńpìlì.”

  • *

    Tàbí “ẹlẹ́wà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:17, 19; Jer 52:12, 13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 368-369

Àìsáyà 64:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 74:10, 11; Sek 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 369-370

Àwọn míì

Àìsá. 64:3Ẹk 34:10
Àìsá. 64:3Hab 3:6
Àìsá. 64:4Sm 130:6-8; Ais 25:9; Mik 7:7; 1Kọ 2:9
Àìsá. 64:5Sef 2:3; Iṣe 10:34, 35
Àìsá. 64:5Ais 1:21; 63:10
Àìsá. 64:6Le 12:2; 15:20
Àìsá. 64:7Di 31:17; Ais 57:17
Àìsá. 64:8Ais 63:16
Àìsá. 64:8Ais 29:16; 45:9; Jer 18:6
Àìsá. 64:9Sm 74:1; 79:5
Àìsá. 64:10Sm 79:1; Ida 1:4; 5:18; Mik 3:12
Àìsá. 64:112Kr 36:17, 19; Jer 52:12, 13
Àìsá. 64:12Sm 74:10, 11; Sek 1:12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 64:1-12

Àìsáyà

64 Ká ní o ti fa ọ̀run ya, tí o sì sọ̀ kalẹ̀,

Kí àwọn òkè lè mì tìtì nítorí rẹ,

 2 Bí ìgbà tí iná ran igi wíwẹ́,

Tí iná sì mú kí omi hó,

Àwọn ọ̀tá rẹ máa wá mọ orúkọ rẹ,

Àwọn orílẹ̀-èdè sì máa gbọ̀n rìrì níwájú rẹ!

 3 Nígbà tí o ṣe àwọn ohun tó ń bani lẹ́rù, tí a ò jẹ́ retí,+

O sọ̀ kalẹ̀, àwọn òkè sì mì tìtì níwájú rẹ.+

 4 Láti ìgbà àtijọ́, kò sẹ́ni tó gbọ́ tàbí tó fetí sílẹ̀,

Kò sí ojú tó rí Ọlọ́run kankan àfi ìwọ,

Tó ń gbé ìgbésẹ̀ nítorí àwọn tó ń retí rẹ̀.*+

 5 O ti bá àwọn tó ń fayọ̀ ṣe ohun tó tọ́ pàdé,+

Àwọn tó ń rántí rẹ, tí wọ́n sì ń tẹ̀ lé àwọn ọ̀nà rẹ.

Wò ó! Inú bí ọ, nígbà tí à ń ṣẹ̀ ṣáá,+

Ó pẹ́ gan-an tí a fi ṣe bẹ́ẹ̀.

Ṣé ó wá yẹ ká rígbàlà báyìí?

 6 Gbogbo wa ti dà bí aláìmọ́,

Gbogbo iṣẹ́ òdodo wa sì dà bí aṣọ tí wọ́n fi ṣe nǹkan oṣù.+

Gbogbo wa máa rọ bí ewé,

Àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa sì máa gbé wa lọ bí atẹ́gùn.

 7 Kò sẹ́ni tó ń pe orúkọ rẹ,

Kò sẹ́ni tó ń ru ara rẹ̀ sókè láti gbá ọ mú,

Torí o ti fi ojú rẹ pa mọ́ fún wa,+

O sì mú ká ṣègbé* torí* ẹ̀ṣẹ̀ wa.

 8 Àmọ́ ní báyìí, Jèhófà, ìwọ ni Bàbá wa.+

Àwa ni amọ̀, ìwọ sì ni Ẹni tó mọ wá;*+

Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa.

 9 Jèhófà, má ṣe bínú jù,+

Má sì rántí àwọn àṣìṣe wa títí láé.

Jọ̀ọ́, wò wá, torí èèyàn rẹ ni gbogbo wa.

10 Àwọn ìlú mímọ́ rẹ ti di aginjù.

Síónì ti di aginjù,

Jerúsálẹ́mù ti di ahoro.+

11 Ilé* wa mímọ́ àti ológo,*

Tí àwọn baba ńlá wa ti yìn ọ́,

Ni wọ́n ti dáná sun,+

Gbogbo àwọn ohun tó ṣeyebíye sí wa sì ti pa run.

12 Pẹ̀lú èyí, ṣé o ṣì máa dúró, Jèhófà?

Ṣé o ṣì máa dákẹ́ jẹ́ẹ́, tí wàá sì jẹ́ kí ìyà jẹ wá gidigidi?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́