ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Sámúẹ́lì

      • Sámúẹ́lì fòróró yan Dáfídì láti jọba lẹ́yìn Sọ́ọ̀lù (1-13)

        • “Jèhófà ń rí ohun tó wà nínú ọkàn” (7)

      • Ẹ̀mí Ọlọ́run kúrò lára Sọ́ọ̀lù (14-17)

      • Dáfídì di ẹni tó ń ta háàpù fún Sọ́ọ̀lù (18-23)

1 Sámúẹ́lì 16:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 15:35
  • +1Sa 15:23, 26
  • +1Ọb 1:39
  • +Rut 4:17; 1Kr 2:12
  • +Jẹ 49:10; 1Sa 13:14; Sm 78:70; Iṣe 13:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2010, ojú ìwé 23

1 Sámúẹ́lì 16:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 22:17

1 Sámúẹ́lì 16:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 89:20

1 Sámúẹ́lì 16:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Rut 4:11; 1Sa 20:6

1 Sámúẹ́lì 16:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:28; 1Kr 2:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2010, ojú ìwé 23

1 Sámúẹ́lì 16:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 10:21, 23
  • +1Ọb 8:39; 1Kr 28:9; Sm 7:9; Owe 24:12; Jer 17:10; Iṣe 1:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2010, ojú ìwé 23

    11/15/2004, ojú ìwé 20

    3/15/2003, ojú ìwé 15

    6/15/1999, ojú ìwé 22

1 Sámúẹ́lì 16:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:13; 1Kr 2:13

1 Sámúẹ́lì 16:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 13:3

1 Sámúẹ́lì 16:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2005, ojú ìwé 9

    9/15/2002, ojú ìwé 30-31

1 Sámúẹ́lì 16:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:14
  • +2Sa 7:8; Sm 78:70

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2011, ojú ìwé 28-29

    10/1/2005, ojú ìwé 9

    9/15/2002, ojú ìwé 30-31

1 Sámúẹ́lì 16:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:42
  • +1Sa 13:14; Sm 89:20; Iṣe 13:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 5 2016 ojú ìwé 9

1 Sámúẹ́lì 16:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 16:1; 1Ọb 1:39
  • +Nọ 11:17; Ond 3:9, 10; 1Sa 10:6; 2Sa 23:2
  • +1Sa 1:1, 19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 5 2016 ojú ìwé 9

1 Sámúẹ́lì 16:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 18:12; 28:15
  • +1Sa 18:10; 19:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2022,

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2005, ojú ìwé 23-24

1 Sámúẹ́lì 16:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 22:29

1 Sámúẹ́lì 16:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìránṣẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:32, 36, 45, 46
  • +1Sa 16:12
  • +1Sa 18:12

1 Sámúẹ́lì 16:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:15

1 Sámúẹ́lì 16:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 22:29

1 Sámúẹ́lì 16:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 16:14; 18:10; 19:9

Àwọn míì

1 Sám. 16:11Sa 15:35
1 Sám. 16:11Sa 15:23, 26
1 Sám. 16:11Ọb 1:39
1 Sám. 16:1Rut 4:17; 1Kr 2:12
1 Sám. 16:1Jẹ 49:10; 1Sa 13:14; Sm 78:70; Iṣe 13:22
1 Sám. 16:21Sa 22:17
1 Sám. 16:3Sm 89:20
1 Sám. 16:4Rut 4:11; 1Sa 20:6
1 Sám. 16:61Sa 17:28; 1Kr 2:13
1 Sám. 16:71Sa 10:21, 23
1 Sám. 16:71Ọb 8:39; 1Kr 28:9; Sm 7:9; Owe 24:12; Jer 17:10; Iṣe 1:24
1 Sám. 16:81Sa 17:13; 1Kr 2:13
1 Sám. 16:92Sa 13:3
1 Sám. 16:111Sa 17:14
1 Sám. 16:112Sa 7:8; Sm 78:70
1 Sám. 16:121Sa 17:42
1 Sám. 16:121Sa 13:14; Sm 89:20; Iṣe 13:22
1 Sám. 16:131Sa 16:1; 1Ọb 1:39
1 Sám. 16:13Nọ 11:17; Ond 3:9, 10; 1Sa 10:6; 2Sa 23:2
1 Sám. 16:131Sa 1:1, 19
1 Sám. 16:141Sa 18:12; 28:15
1 Sám. 16:141Sa 18:10; 19:9
1 Sám. 16:16Owe 22:29
1 Sám. 16:181Sa 17:32, 36, 45, 46
1 Sám. 16:181Sa 16:12
1 Sám. 16:181Sa 18:12
1 Sám. 16:191Sa 17:15
1 Sám. 16:21Owe 22:29
1 Sám. 16:231Sa 16:14; 18:10; 19:9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Sámúẹ́lì 16:1-23

Sámúẹ́lì Kìíní

16 Níkẹyìn, Jèhófà sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Ìgbà wo lo máa ṣọ̀fọ̀ Sọ́ọ̀lù dà,+ ní báyìí tí mo ti kọ Sọ́ọ̀lù pé kí ó má ṣe jẹ́ ọba lórí Ísírẹ́lì mọ́?+ Rọ òróró sínú ìwo,+ kí o sì lọ. Màá rán ọ lọ sọ́dọ̀ Jésè+ ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, nítorí mo ti yan ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ láti jẹ́ ọba fún mi.”+ 2 Àmọ́ Sámúẹ́lì sọ pé: “Báwo ni màá ṣe lọ? Tí Sọ́ọ̀lù bá gbọ́ nípa rẹ̀, yóò pa mí.”+ Jèhófà fèsì pé: “Mú abo ọmọ màlúù kan dání, kí o sì sọ pé, ‘Mo wá rúbọ sí Jèhófà ni.’ 3 Pe Jésè síbi ẹbọ náà; màá sì jẹ́ kí o mọ ohun tí o máa ṣe. Kí o bá mi fòróró yan ẹni tí mo bá tọ́ka sí fún ọ.”+

4 Sámúẹ́lì ṣe ohun tí Jèhófà sọ. Nígbà tó dé Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+ ẹ̀rù ń ba àwọn àgbààgbà ìlú nígbà tí wọ́n wá pàdé rẹ̀, wọ́n sọ pé: “Ṣé àlàáfíà lo bá wá?” 5 Ó fèsì pé: “Àlàáfíà ni. Mo wá rúbọ sí Jèhófà ni. Ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì bá mi lọ síbi ẹbọ náà.” Ó wá ya Jésè àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sí mímọ́, lẹ́yìn náà ó pè wọ́n síbi ẹbọ náà. 6 Bí wọ́n ṣe wọlé, tí ó sì rí Élíábù,+ ó sọ pé: “Ó dájú pé ẹni àmì òróró Jèhófà ló dúró yìí.” 7 Ṣùgbọ́n Jèhófà sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Má wo ìrísí rẹ̀ àti bí ó ṣe ga tó,+ torí pé mo ti kọ̀ ọ́. Nítorí ọ̀nà tí èèyàn gbà ń wo nǹkan kọ́ ni Ọlọ́run gbà ń wo nǹkan, torí pé ohun tí ó bá hàn síta ni èèyàn ń rí, ṣùgbọ́n Jèhófà ń rí ohun tó wà nínú ọkàn.”+ 8 Jésè bá pe Ábínádábù,+ ó sì ní kí ó kọjá níwájú Sámúẹ́lì, àmọ́ ó sọ pé: “Jèhófà kò yan eléyìí náà.” 9 Lẹ́yìn náà, Jésè mú Ṣámà wá,+ ṣùgbọ́n ó sọ pé: “Jèhófà kò yan eléyìí náà.” 10 Nítorí náà, Jésè mú kí méje lára àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ kọjá níwájú Sámúẹ́lì, àmọ́ Sámúẹ́lì sọ fún Jésè pé: “Jèhófà kò yan ìkankan lára wọn.”

11 Níkẹyìn, Sámúẹ́lì béèrè lọ́wọ́ Jésè pé: “Ṣé gbogbo àwọn ọmọkùnrin rẹ nìyí?” Ó fèsì pé: “Èyí tó kéré jù+ ṣì wà níta; ó kó àwọn àgùntàn lọ jẹ koríko.”+ Ni Sámúẹ́lì bá sọ fún Jésè pé: “Ní kí wọ́n lọ pè é wá, torí ó dìgbà tó bá dé ká tó jókòó láti jẹun.” 12 Torí náà, ó ránṣẹ́ pè é, ó sì mú un wọlé. Ọmọ náà pupa, ẹyinjú rẹ̀ mọ́ lóló, ó sì rẹwà gan-an.+ Ni Jèhófà bá sọ pé: “Dìde, fòróró yàn án, torí òun nìyí!”+ 13 Torí náà, Sámúẹ́lì mú ìwo tí òróró wà nínú rẹ̀,+ ó sì fòróró yàn án lójú àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀. Ẹ̀mí Jèhófà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fún Dáfídì lágbára láti ọjọ́ náà lọ.+ Lẹ́yìn náà, Sámúẹ́lì dìde, ó sì gba Rámà lọ.+

14 Àmọ́ ní ti Sọ́ọ̀lù, ẹ̀mí Jèhófà ti kúrò lára rẹ̀,+ Jèhófà sì jẹ́ kí ẹ̀mí búburú máa dà á láàmú.+ 15 Àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù bá sọ fún un pé: “O ò rí i pé Ọlọ́run ti ń jẹ́ kí ẹ̀mí búburú máa dà ọ́ láàmú. 16 Jọ̀ọ́, jẹ́ kí olúwa wa pàṣẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó wà níwájú rẹ̀ pé kí wọ́n wá ọkùnrin tó mọ háàpù ta dáadáa.+ Ìgbàkígbà tí Ọlọ́run bá ti jẹ́ kí ẹ̀mí búburú dà ọ́ láàmú, yóò ta háàpù náà, ara rẹ á sì balẹ̀.” 17 Nítorí náà, Sọ́ọ̀lù sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ẹ jọ̀wọ́, ẹ bá mi wá ọkùnrin kan tó mọ háàpù ta dáadáa, kí ẹ sì mú un wá sọ́dọ̀ mi.”

18 Ọ̀kan lára àwọn ẹmẹ̀wà* sọ pé: “Wò ó! Mo ti rí bí ọ̀kan lára àwọn ọmọ Jésè ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ṣe ń ta háàpù dáadáa, onígboyà ni, jagunjagun tó lákíkanjú sì ni.+ Ó mọ̀rọ̀ọ́ sọ, ó rẹwà,+ Jèhófà sì wà pẹ̀lú rẹ̀.”+ 19 Ni Sọ́ọ̀lù bá rán àwọn òjíṣẹ́ sí Jésè pé: “Fi Dáfídì ọmọ rẹ tó wà pẹ̀lú agbo ẹran ránṣẹ́ sí mi.”+ 20 Nítorí náà, Jésè gbé oúnjẹ àti wáìnì ìgò awọ kan pẹ̀lú ọmọ ewúrẹ́, ó dì wọ́n sórí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ó sì fi wọ́n ránṣẹ́ pẹ̀lú Dáfídì ọmọ rẹ̀ sí Sọ́ọ̀lù. 21 Bí Dáfídì ṣe wá sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù nìyẹn, tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìránṣẹ́ rẹ̀.+ Sọ́ọ̀lù wá nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ gan-an, ó sì yàn án pé kó máa gbé ìhámọ́ra òun. 22 Sọ́ọ̀lù ránṣẹ́ sí Jésè pé: “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí Dáfídì máa ṣe ìránṣẹ́ mi nìṣó, torí ó ti rí ojú rere mi.” 23 Ìgbàkígbà tí Ọlọ́run bá ti jẹ́ kí ẹ̀mí búburú mú Sọ́ọ̀lù, Dáfídì á mú háàpù, á sì ta á, ìtura á bá Sọ́ọ̀lù, ara rẹ̀ á balẹ̀, ẹ̀mí búburú náà á sì fi í sílẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́