Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jóẹ́lì JÓẸ́LÌ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Àwọn kòkòrò ṣọṣẹ́ gan-an (1-14) “Ọjọ́ Jèhófà sún mọ́lé” (15-20) Wòlíì náà ké pe Jèhófà (19, 20) 2 Ọjọ́ Jèhófà àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ (1-11) Ìkésíni láti pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà (12-17) “Ọkàn yín ni kí ẹ fà ya” (13) Ohun tí Jèhófà sọ fún àwọn èèyàn rẹ̀ (18-32) “Èmi yóò tú ẹ̀mí mi” (28) Àwọn ohun ìyanu lójú ọ̀run àti ní ayé (30) Àwọn tó ń ké pe orúkọ Jèhófà yóò rí ìgbàlà (32) 3 Jèhófà dá gbogbo orílẹ̀-èdè lẹ́jọ́ (1-17) Àfonífojì Jèhóṣáfátì (2, 12) Àfonífojì ìpinnu (14) Jèhófà jẹ́ odi ààbò Ísírẹ́lì (16) Jèhófà ń bù kún àwọn èèyàn rẹ̀ (18-21)