MÁÀKÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-
A yí Jésù pa dà di ológo (1-13)
Ó wo ọmọkùnrin tí ẹ̀mí èṣù ń yọ lẹ́nu sàn (14-29)
Ohun gbogbo ṣeé ṣe fún ẹni tó ní ìgbàgbọ́ (23)
Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (30-32)
Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń jiyàn nípa ẹni tó tóbi jù (33-37)
Ẹni tí kò bá ta kò wá, tiwa ló ń ṣe (38-41)
Àwọn ohun ìkọ̀sẹ̀ (42-48)
“Ẹ ní iyọ̀ nínú ara yín” (49, 50)
-
Ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ (1-12)
Jésù súre fún àwọn ọmọdé (13-16)
Ìbéèrè ọkùnrin ọlọ́rọ̀ (17-25)
Àwọn ohun tí a yááfì torí Ìjọba náà (26-31)
Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (32-34)
Ohun tí Jémíìsì àti Jòhánù béèrè (35-45)
Jésù fi ẹ̀mí rẹ̀ ṣe ìràpadà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn (45)
Ó wo Báátíméù afọ́jú sàn (46-52)
-
Àwọn àlùfáà gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù (1, 2)
Ó da òróró onílọ́fínńdà sórí Jésù (3-9)
Júdásì da Jésù (10, 11)
Ìrékọjá tó gbẹ̀yìn (12-21)
Jésù fi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa lọ́lẹ̀ (22-26)
Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (27-31)
Jésù gbàdúrà ní Gẹ́tísémánì (32-42)
Wọ́n mú Jésù (43-52)
Wọ́n gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (53-65)
Pétérù sẹ́ Jésù (66-72)
-
Jésù jíǹde (1-8)