Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Tímótì 2 TÍMÓTÌ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ìkíni (1, 2) Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run torí ìgbàgbọ́ Tímótì (3-5) Jẹ́ kí ẹ̀bùn Ọlọ́run máa jó bí iná (6-11) Máa tẹ̀ lé àwọn ọ̀rọ̀ tó ṣàǹfààní (12-14) Àwọn ọ̀tá Pọ́ọ̀lù àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ (15-18) 2 Fi ọ̀rọ̀ náà síkàáwọ́ àwọn ọkùnrin tó kúnjú ìwọ̀n (1-7) Jìyà nítorí ìhìn rere (8-13) Máa lo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run bó ṣe yẹ (14-19) Sá fún àwọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ìgbà ọ̀dọ́ (20-22) Ohun tí o lè ṣe sí àwọn alátakò (23-26) 3 Nǹkan máa le gan-an ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn (1-7) Tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù pẹ́kípẹ́kí (8-13) “Má ṣe fi àwọn nǹkan tí o ti kọ́ sílẹ̀” (14-17) Gbogbo Ìwé Mímọ́ ni Ọlọ́run mí sí (16) 4 “Ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ láìkù síbì kan” (1-5) Wàásù ọ̀rọ̀ náà láìfi falẹ̀ (2) “Mo ti ja ìjà rere náà” (6-8) Àwọn ọ̀rọ̀ ara ẹni (9-18) Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (19-22)