Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Jòhánù 2 JÒHÁNÙ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ Ìkíni (1-3) Máa rìn nínú òtítọ́ (4-6) Ṣọ́ra fún àwọn ẹlẹ́tàn (7-11) Ẹ má ṣe kí i (10, 11) Ìbẹ̀wò tó fẹ́ ṣe àti ìkíni (12, 13)