ÌBÉÈRÈ 4
Ṣé Bíbélì máa ń tọ̀nà tó bá sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì?
“Ó na òfúrufú apá àríwá sórí ibi tó ṣófo, ó fi ayé rọ̀ sórí òfo.”
“Gbogbo odò ló ń ṣàn lọ sínú òkun, síbẹ̀ òkun kò kún. Ibi tí àwọn odò ti ṣàn wá, ibẹ̀ ni wọ́n ń pa dà sí, kí wọ́n tún lè ṣàn jáde.”
“Ẹnì kan wà tó ń gbé orí òbìrìkìtì ayé.”