Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè
1. Símónì ará Kírénè
2. “Ọmọ ènìyàn”
3. Ọkọ́
4. Ìfẹ́
5. Yóò sẹ́ pé òun kò mọ Jésù
6. Mánásè
7. “Bí ẹni tí ó kéré jù”
8. Ìdarí ẹ̀mí Ọlọ́run ló tẹ̀ lé; irú ìgbéyàwó bẹ́ẹ̀ yóò fún un láǹfààní láti bá àwọn Filísínì jà
9. Pé kí a gbé wọn kọ́ níwájú àwọn ènìyàn bí a ti ṣe fún bàbá wọn láti bẹ̀tẹ́ lù wọ́n
10. Baálẹ̀
11. A óò ké ọjọ́ wọ̀nnì kúrú
12. Kíkúrò ní Íjíbítì lọ sí Ilẹ̀ Ìlérí
13. Nímírọ́dù
14. Ṣémérì
15. Lísírà
16. Ṣíméì ọmọ ìran Bẹ́ńjámínì
17. Tígírísì (Hídẹ́kẹ́lì)
18. Sínárì