TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Wà ní Mímọ́ Tónítóní àti Létòlétò
Àwọn ọmọdé lè kọ́ ẹ̀kọ́ pàtàkì nínú eré bèbí yìí.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)
OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọdún Kérésìmesì?
Ibi tí àwọn nǹkan tí wọ́n ń ṣe lákòókò Kérésìmesì ti wá máa yà ẹ́ lẹ́nu.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ > Àwọn ayẹyẹ)