Tún Lọ Wo Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ
Àwọn àbá tá a jíròrò nínú àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ kó o rí bí ṣíṣe àníyàn ṣe lè ṣé ẹ́ láǹfààní dípò tá a fi ṣèpalára fún ẹ.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
Àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ kó o mọ bí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe máa ń ran ara wọn àtawọn míì lọ́wọ́.
(Wo abẹ́ NÍPA WA > ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ)