Ka Àpilẹ̀kọ Tó Kù Lórí Ìkànnì
FÍDÍÒ
Ó ń ṣe ẹ́ bíi pé ìwọ náà ti ń gòkè àgbà, ó sì wù ẹ́ káwọn òbí ẹ bẹ̀rẹ̀ sí í fún ẹ láwọn àǹfààní kan, àmọ́ àwọn òbí ẹ sọ pé kò tíì tó àkókò. Àwọn nǹkan wo lo lè ṣe tó máa jẹ́ kí wọ́n túbọ̀ fọkàn tán ẹ?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Tó bá jẹ́ pé àwọn èèyàn ló kọ Bíbélì, ṣé a lè sọ pé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni lóòótọ́?
(Wo abẹ́ ÀWỌN ÌTẸ̀JÁDE > ÀWỌN FÍDÍÒ, ní apá náà “Bíbélì”)