Ka Àpilẹ̀kọ Tó Kù Lórí Ìkànnì
Kárí ayé làwọn èèyàn ti mọ̀ pé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kì í lọ sójú ogun. Kà nípa ìdí tí a kì í fi í lọ sójú ogun.
(Wo abẹ́ NÍPA WA > ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ)
Ní ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ nígbà àjálù.
(Wo abẹ́ NÍPA WA > OHUN TÁ À Ń ṢE)