Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí?
Jesu Kristi ha ni Ọlọrun Olodumare bi?
A Tún Un Tẹ̀ ní Ọdún 2006
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Ayafi bi a ba fihan pe omiran ni, gbogbo ayọlo Mimọ wá lati inu Bibeli Yoruba, itẹjade ti 1969.