Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi?
Bi ó bá rí bẹẹ, eeṣe ti oun fi fayegba ijiya?
Yoo ha dopin lae bi?
A Tún Un Tẹ̀ ní Ọdún 2006
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Awọn ẹsẹ Bibeli ti a fayọ ninu iwe yii jẹ lati inu Bibeli Mimọ ni èdè Yoruba, itẹjade ti 1960, ayafi bi a bá fihan pe omiran ni. Nibi ti a bá ti fi NW han tẹle ẹsẹ Bibeli kan ti a fayọ, o ń fihan pe a ti tumọ ẹsẹ naa lati inu Bibeli èdè Gẹẹsi, itumọ ode-oni ti New World Translation of the Holy Scriptures —With References, Ẹ̀dà ti 1984