Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ìmọ̀ Ẹ̀kọ́
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa donate.jw.org.
Ìtumọ̀ Bíbélì ti Ìwé Mímọ́ Kristian Lédè Griki ní Ìtumọ̀ Ayé Titun ni a lò fún Ìwé Mímọ́ Lédè Gíríìkì, ìtumọ̀ tí a sì lò fún Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù ni Bibeli Mimọ ní èdè Yorùbá. A ti mú ìtumọ̀ méjèèjì bá àkọtọ́ ti òde òní mu. Níbi tí NW bá ti tẹ̀ lé àyọlò, ó fi hàn pé ìtumọ̀ náà wá láti inú Bíbélì New World Translation of the Holy Scriptures—With References
A tẹ̀ ẹ́ ní March 2024
Yoruba (ed-YR)
© 1996, 2003, 2024 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania