Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Ìwé kan tí ó Wà fún Gbogbo Ènìyàn
A Tún Un Tẹ̀ ní Ọdún 2006
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Bí a kò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi èdè tí ó bóde mu túmọ̀. Níbi tí NW bá ti tẹ̀ lé àyọlò, ó fi hàn pé ìtumọ̀ náà wá láti inú Bíbélì New World Translation of the Holy Scriptures—With References
[Àwọn àwòrán Credit Line]
Ojú ìwé 3 Heinrich Heine: Archive Photos;
ojú ìwé 4 àwọn awò awọ̀nàjíjìn: © Gianni Tortoli, Science Source/Photo Researchers;
ojú ìwé 5 a bi Galileo léèrè ọ̀rọ̀: Erich Lessing/Art Resource, NY;
ojú ìwé 6 Nípasẹ̀ Ìyọ̀ǹda Ibi Ìkówèésí ti Britain/Gutenberg Bible; ẹ̀rọ ìtẹ̀wé: Ìyọ̀ǹda onínúure ti American Bible Society;
ojú ìwé 9 ìṣà: Bibelmuseum, Münster;
ojú ìwé 11 Robert Moffat: Culver Pictures;
ojú ìwé 12 Adoniram Judson: John C. Buttre/Dictionary of American Portraits/Dover ni ó gbẹ́ ẹ;
ojú ìwé 13 Robert Morrison: Corbis-Bettmann;
ojú ìwé 15 àfọ́kù ti Tel Dan: HUC, Tel Dan Excavations; fọ́tò: Zeev Radovan;
ojú ìwé 16, 17 àwòrán gbígbẹ́: Ẹ̀tọ́ Jẹ́ ti The Trustees of the British Museum, British Museum Press;
ojú ìwé 18 Ilẹ̀ Ayé: Fọ́tò NASA;
ojú ìwé 29 Bábílónì: Fọ́tò WHO láti ọwọ́ Edouard Boubat