Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Orí
1 Ohun Tó Mú Kí Jésù Jẹ́ Olùkọ́ Ńlá
2 Lẹ́tà Kan Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Tó Fẹ́ràn Wa
6 Olùkọ́ Ńlá Náà Sin Àwọn Ẹlòmíràn
8 Àwọn Kan Wà Nípò Tó Ga Ju Tiwa Lọ
10 Agbára Jésù Ju Ti Àwọn Ẹ̀mí Èṣù Lọ
11 Ìrànlọ́wọ́ Látọ̀dọ̀ Àwọn Áńgẹ́lì Ọlọ́run
12 Jésù Kọ́ Wa Bí A Ó Ṣe Máa Gbàdúrà
14 Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dárí Jini
18 Ǹjẹ́ O Máa Ń Rántí Láti Dúpẹ́?
20 Ǹjẹ́ O Máa Ń Fẹ́ Jẹ́ Ẹni Àkọ́kọ́ Nígbà Gbogbo?
22 Ìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Máa Purọ́
23 Ìdí Tí Àwọn Èèyàn Fi Ń Ṣàìsàn
25 Ǹjẹ́ Àwọn Tó Ń Ṣe Ohun Búburú Lè Yí Padà?
26 Ìdí Tó Fi Nira Láti Máa Ṣe Rere
28 Bí A Ṣe Lè Mọ Ẹni Tó Yẹ Kí Á Ṣègbọràn Sí
29 Ǹjẹ́ Gbogbo Àpèjẹ Ni Inú Ọlọ́run Dùn Sí?
30 Ìrànlọ́wọ́ Láti Borí Ìbẹ̀rù
31 Ibi Tí A Ti Lè Rí Ìtùnú Gbà
32 Bí Ọlọ́run Ṣe Dáàbò Bo Jésù
34 Kí Ni Yóò Ṣẹlẹ̀ Bí A Bá Kú?
35 A Lè Jí Dìde Kúrò Nínú Ikú!
36 Àwọn Wo Ni A Óò Jí Dìde? Ibo Ni Wọn Yóò Máa Gbé?
37 Bí A Ṣe Lè Rántí Jèhófà àti Ọmọ Rẹ̀
38 Ìdí Tó Fi Yẹ Kí Á Fẹ́ràn Jésù
40 Bí A Ṣe Lè Mú Inú Ọlọ́run Dùn
41 Àwọn Ọmọdé Tó Mú Inú Ọlọ́run Dùn
43 Àwọn Wo Ni Arákùnrin àti Arábìnrin Wa?
44 Ó Yẹ Kí Àwọn Ọ̀rẹ́ Wa Fẹ́ràn Ọlọ́run
45 Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? Bí A Ṣe Lè Fi Hàn Pé À Ń Fẹ́ Ẹ
46 Omi Pa Ayé Kan Run—Ǹjẹ́ Irú Ẹ̀ Tún Lè Ṣẹlẹ̀ Mọ́?