Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Ojú Ìwé Orí
4 1 “Mo Ti Fi Ọ̀rọ̀ Mi sí Ẹnu Rẹ”
14 2 Ṣíṣe Iṣẹ́ Ọlọ́run ní “Apá Ìgbẹ̀yìn Àwọn Ọjọ́”
32 3 “Kí O sì Sọ Ọ̀rọ̀ Yìí fún Wọn”
43 4 Ṣọ́ra fún Ọkàn Tó Ń Ṣàdàkàdekè
54 5 Àwọn Wo Ló Yẹ Kó O Yàn Lọ́rẹ̀ẹ́?
67 6 “Jọ̀wọ́, Ṣègbọràn sí Ohùn Jèhófà”
81 7 “Ọkàn Tí Àárẹ̀ Mú Ni Èmi Yóò Tẹ́ Lọ́rùn ní Kíkún”
92 8 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jeremáyà Kó O Lè “Máa Wà Láàyè Nìṣó”
103 9 Má Ṣe “Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ”
114 10 Ǹjẹ́ O Máa Ń Béèrè Lójoojúmọ́ Pé, “Jèhófà Dà?”
128 11 ‘Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn ní Ìbámu Pẹ̀lú Ọkàn-àyà Mi’
140 12 “Ìyẹn Kì Í Ha Ṣe Ọ̀ràn Mímọ̀ Mí Bí?”
154 13 “Jèhófà Ti Ṣe Ohun Tí Ó Ní Lọ́kàn”