Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!
A Tẹ̀ Ẹ́ ní October 2019
Yoruba (fg-YR)
© 2012
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
Ibi Tá A Ti Mú Àwọn Àwòrán:
Ojú ìwé 6, lápá òkè, Àkájọ Ìwé Òkun Òkú: Shrine of the Book, Photo © The Israel Museum, Jerusalem; ojú ìwé 6, láàárín àti ojú ìwé 32, lápá ọ̀tún lókè pátápátá, Greek Codex: Látinú The Codex Alexandrinus in Reduced Photographic Facsimile, 1909, àwọn British Library ló fún wa láṣẹ láti lò ó; ojú ìwé 16, Hitler: Látinú àwọn fọ́tò U.S. National Archives