Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀
© 2014
Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvanai
Àwa Òǹṣèwé
Watchtower Bible and Tract Society of New York, Inc. Brooklyn, New York, U.S.A.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní April 2014
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ.