Àfikún Àlàyé Tó Wúlò fún Ìdílé Wà Lórí jw.org
Jọ̀wọ́ lọ wo ìkànnì wa kí o lè rí àfikún ìmọ̀ràn tó wúlò àti ọgbọ́n látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. O tún máa lè ka ìrírí àwọn tọkọtaya míì yíká ayé níbẹ̀.
Máa bọ̀wọ̀ fún ọkọ tàbí aya rẹ
Bí ẹ ṣe lè yẹra fún sísọ ọ̀rọ̀ líle síra yín
Bí ẹ ṣe lè jáwọ́ nínú bíbá ara yín jiyàn
Bí ẹ ṣe lè máa dárí ji ara yín
Bí ọ̀rẹ́ ìwọ àtẹnì kan bá ti ń wọra jù
Bí ọkọ tàbí aya rẹ bá nílò àbójútó àrà ọ̀tọ̀
Bí àwọn tó tún ìgbéyàwó ṣe ṣe lè ṣàṣeyọrí
Bó o ṣe lè bójú tó ọmọ tó ń ṣe ìjọ̀ngbọ̀n
Ohun tí ẹ lè ṣe tí ọmọ yín bá jẹ́ abirùn
Bá ọmọ rẹ sọ̀rọ̀ nípa ìbálòpọ̀
Kí lo lè ṣe bí ọmọ rẹ tó ti bàlágà bá ń ṣiyè méjì nípa ẹ̀sìn rẹ?
Bó o ṣe lè ran àwọn ọmọ rẹ lọ́wọ́ nígbà tí wọ́n bá ń bàlágà
Bí ọmọ rẹ tí kò tíì pé ogún ọdún bá ń dọ́gbẹ́ sí ara rẹ̀ (Lédè Gẹ̀ẹ́sì)
Bí àárín àwọn tó tún ìgbéyàwó ṣe àti àwọn ẹlòmíì ṣe lè tòrò
A tún máa ń fi àwọn míì kún un déédéé.