Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
ORÍ OJÚ ÌWÉ
6 1 A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà
12 2 Mọyì Ipa Tí Kristi Ń Kó Nínú Ìṣètò Ọlọ́run
17 3 “Ẹ Máa Rántí Àwọn Tó Ń Mú Ipò Iwájú Láàárín Yín”
24 4 Bá A Ṣe Ṣètò Ìjọ àti Bá A Ṣe Ń Darí Rẹ̀
30 5 Àwọn Alábòójútó Tó Ń Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo
53 6 Àwọn Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ń Ṣe Ìjọ Láǹfààní
59 7 Àwọn Ìpàdé Tó Ń Fún “Wa Níṣìírí Láti Ní Ìfẹ́ àti Láti Ṣe Àwọn Iṣẹ́ Rere”
71 8 Àwọn Òjíṣẹ́ Tó Ń Wàásù Ìhìn Rere
87 9 Àwọn Ọ̀nà Tá À Ń Gbà Wàásù Ìhìn Rere
105 10 Àwọn Ọ̀nà Tó O Lè Gbà Mú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Gbòòrò Sí I
116 11 Bá A Ṣe Ṣètò Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa
123 12 Bá A Ṣe Ń Ti Iṣẹ́ Ìwàásù Lẹ́yìn ní Ìjọ Kọ̀ọ̀kan àti Kárí Ayé
130 13 “Ẹ Máa Ṣe Ohun Gbogbo fún Ògo Ọlọ́run”
141 14 Bá A Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ìjọ Wà ní Mímọ́ Kí Àlàáfíà sì Jọba
157 15 Àǹfààní Tá À Ń Rí Bí Ọlọ́run Ṣe Ń Darí Wa
162 16 Ẹgbẹ́ Ará Tó Wà Níṣọ̀kan
169 17 Má Ṣe Fi Ètò Jèhófà Sílẹ̀
179 Àfikún
185 Ìbéèrè Tá A Máa Ń Bi Àwọn Tó Fẹ́ Ṣèrìbọmi—Apá Kìíní: Ohun Táwọn Kristẹni Gbà Gbọ́
193 Ìbéèrè Tá A Máa Ń Bi Àwọn Tó Fẹ́ Ṣèrìbọmi—Apá Kejì: Ìgbé Ayé Kristẹni
206 Ìbéèrè Tá A Máa Ń Bi Àwọn Tó Fẹ́ Ṣèrìbọmi—Ìjíròrò Tó Kẹ́yìn Pẹ̀lú Àwọn Tó Fẹ́ Ṣèrìbọmi