Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Ṣíṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́—2017
Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ti Ọdún Yìí “Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa ṣe rere.”—Sáàmù 37:3.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní August 2016
Yoruba (es17-YR)
© 2016
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA