Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
APÁ ORÍ OJÚ ÌWÉ
ÌBẸ̀RẸ̀
1. “Jèhófà Ọlọ́run Rẹ Ni O Gbọ́dọ̀ Jọ́sìn” 6
2. “Ọlọ́run Fọwọ́ Sí” Àwọn Ẹ̀bùn Wọn 15
APÁ 1
3. ‘Mo Rí Ìran Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run’ 30
4. Àwọn Wo Ni “Ẹ̀dá Alààyè Tó Ní Ojú Mẹ́rin Náà”? 42
APÁ 2
Ẹ TI “SỌ IBI MÍMỌ́ MI DI ALÁÌMỌ́”—WỌ́N SỌ ÌJỌSÌN MÍMỌ́ DI ẸLẸ́GBIN 51
5. ‘Wo Iṣẹ́ Ibi Tó Ń Ríni Lára Tí Wọ́n Ń Ṣe’ 52
6. “Òpin Ti Dé Bá Yín Báyìí” 62
7. Àwọn Orílẹ̀-Èdè “Á sì Wá Mọ̀ Pé Èmi Ni Jèhófà” 71
APÁ 3
‘MÀÁ KÓ YÍN JỌ’—ỌLỌ́RUN ṢÈLÉRÍ PÉ WỌ́N Á TÚN PA DÀ ṢE ÌJỌSÌN MÍMỌ́ 83
8. “Èmi Yóò Yan Olùṣọ́ Àgùntàn Kan” 84
9. “Èmi Yóò Mú Kí Ọkàn Wọn Ṣọ̀kan” 95
11. “Mo Ti Fi Ọ́ Ṣe Olùṣọ́” 121
12. “Èmi Yóò Sọ Wọ́n Di Orílẹ̀-Èdè Kan” 129
13. “Ṣàlàyé Bí Tẹ́ńpìlì Náà Ṣe Rí” 137
14. “Òfin Tẹ́ńpìlì Náà Nìyí” 148
APÁ 4
“ÈMI YÓÒ FI ÌTARA GBÈJÀ ORÚKỌ MÍMỌ́ MI”—ÌJỌSÌN MÍMỌ́ BORÍ ÀTAKÒ 161
15. “Èmi Yóò Fòpin sí Iṣẹ́ Aṣẹ́wó Rẹ” 162
16. “Sàmì sí Iwájú Orí” Wọn 172
17. “Èmi Yóò Bá Ọ Jà, Ìwọ Gọ́ọ̀gù” 181
18. “Inú Á Bí Mi Gidigidi” 189
APÁ 5
‘ÈMI YÓÒ MÁA GBÉ NÍ ÀÁRÍN ÀWỌN ÈÈYÀN NÁÀ’—ÌJỌSÌN MÍMỌ́ JÈHÓFÀ PA DÀ BỌ̀ SÍPÒ 201
19. ‘Gbogbo Ohun Tó Wà Níbi tí Omi Náà Ṣàn Dé Yóò Máa Wà Láàyè’ 202
20. “Pín Ilẹ̀ Náà Bí Ogún” 211
21. “Orúkọ Ìlú Náà Yóò Máa Jẹ́ Jèhófà Wà Níbẹ̀” 218