Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Ṣíṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́—2020
Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ti Ọdún Yìí “Torí náà, ẹ lọ, kí ẹ máa sọ àwọn èèyàn . . . di ọmọ ẹ̀yìn, ẹ máa batisí wọn.”—Mátíù 28:19.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
Ṣíṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́—2020
Examining the Scriptures Daily—2020
A Tẹ̀ Ẹ́ ní July 2019
Yoruba (es20-YR)
© 2019
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA