ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w91 6/15 ojú ìwé 32
  • “Ẹyọ Iṣẹ́-ọnà Titobilọla Kan”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ẹyọ Iṣẹ́-ọnà Titobilọla Kan”
  • Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
w91 6/15 ojú ìwé 32

“Ẹyọ Iṣẹ́-ọnà Titobilọla Kan”

Eyiini ni apejuwe tí a fun iwe naa Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye. “Mo wulẹ fẹ́ lati dupẹ lọwọ yin fun ‘okuta iyebiye’ tí ó dé gbẹhin yii,” ni iya kan lati South Wales, ní Britain, kọwe. “Ó jẹ́ ẹyọ iṣẹ́-ọnà titobilọla kan tí mo nimọlara pe kò lẹgbẹ gẹgẹbi àrànṣe fun ikọnilẹkọọ kan . . . Emi kò tíì rí awọn apejuwe tí wọn rẹwà tí wọn sì ńwọnilára tobẹẹ rí. Emi ńlò awọn wọnyi lati kọ́ ọmọbinrin mi ọlọdun meji lẹkọọ ọpọ awọn otitọ ati ìlànà-ìpilẹ̀ rere Bibeli.”

Iwe olójú-iwé 256 yii, tí fífẹ̀ rẹ̀ rí bii ti iwe-irohin yii, kún fun apejuwe ikọnilẹkọọ tí ó jú 150 lọ, tí pupọ julọ ninu wọn jẹ́ aláwọ̀ mèremère. Iwọ lè ní itẹjade titayọ, tí a dì daradara, tí ó lọ́rọ̀ yii nipa kikọ ọrọ kún alafo isalẹ yii kí o sì gé e ranṣẹ sí wa.

Emi yoo fẹ lati gba iwe ẹlẹhin lile naa Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye. (Kọwe si adirẹsi ti nbẹ nisalẹ fun isọfunni.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́