Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
◼ Báwo lo ṣe lè mọ ọ̀nà tó yẹ kó o tọ̀ nínú ìrìn àjò ìgbésí ayé? Wo ojú ìwé 8.
◼ Ǹjẹ́ àwọn tó ṣàkọsílẹ̀ ẹ̀kọ́ Jésù kọ ọ́ lọ́nà tó pé pérépéré? Wo ojú ìwé 12.
◼ Báwo lọmọ orílẹ̀-èdè Ukraine tó ń sọ èdè Jámánì ṣe dẹni tó ń wàásù lábúlé kékeré kan lórílẹ̀-èdè Paraguay? Wo ojú ìwé 19.
◼ Ǹjẹ́ àtúnṣe wà fún ayé tó túbọ̀ ń móoru yìí? Wo ojú ìwé 26.