ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w08 10/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
w08 10/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Ṣé Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ nípa àwọn ìṣòro tó ń bá wa fínra lóde òní? Wo ojú ìwé 6.

◼ Ṣé a lè fara wé Ọlọ́run? Tó bá ṣeé ṣe, báwo la ṣe lè fara wé e? Wo ojú ìwé 15.

◼ Kí làwọn ọmọ nílò látọ̀dọ̀ bàbá wọn? Wo ojú ìwé 18.

◼ Kí la lè kọ́ lára Màríà nípa àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà tó bí Jésù? Wo ojú ìwé 22.

◼ Ẹni pípé ṣáà ni Ádámù, báwo ló ṣe wá dẹ́ṣẹ̀? Wo ojú ìwé 27.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́