Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January 1, 2010
Ojú Wo Ni Ọlọ́run Fi Ń Wo Ọtí Mímu?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
4 Ojú Wo Ni Ọlọ́run Fi Ń Wo Ọtí Mímu?
6 Èrò Tó Yẹ Kó O Ní Nípa Ọtí Mímu
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
11 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
12 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ẹni Tó Ń Mú Ìlérí Ṣẹ
24 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Ó Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Ìdánwò
29 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Ọkùnrin Onírẹ̀lẹ̀ àti Onígboyà
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
13 Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Kọjú Ìjà sí Àwọn Ọmọ Kénáánì?
16 Bí Ìgbésí Ayé àti Àsìkò Àwọn Kristẹni—Àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ Ṣe Rí—Ilé Tí Wọ́n Ń Gbé
19 Ṣé Òkú Lè Ran Àwọn Alààyè Lọ́wọ́?