Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 1, 2010
Ṣé Òpin Ayé Ti Sún Mọ́lé?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Kí Ló Ń Ba Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́rù?
5 Ìdáhùn sí Ìbéèrè Mẹ́rin Nípa Òpin Ayé
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bí O Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Nínú Ọdún Àkọ́kọ́ Ìgbéyàwó
14 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Kí Nìdí Tí Jésù Kò Fi Kánjú
16 Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Bí A Ṣe Lè Láyọ̀
18 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
22 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
23 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
27 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Gbé Ọmọkùnrin Rẹ”
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
24 Bí Ìgbésí Ayé àti Àsìkò Àwọn Kristẹni Àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ Ṣe Rí—“Káfíńtà”
28 A Rán Àwọn Míṣọ́nnárì Jáde Láti Sọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn