Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 1, 2010
Ohun Méje Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Àdúrà
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
Ohun Méje Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Àdúrà
3 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Gbàdúrà?
6 Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà?
9 Ibo La Ti Máa Gbàdúrà, Ìgbà Wo La sì Máa Gbà Á?
10 Ǹjẹ́ Àdúrà Lè Ràn Wá Lọ́wọ́?
11 Ṣé Ọlọ́run Máa Ń Dáhùn Àdúrà Wa?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
13 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
14 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Ó “Ń Bá A Lọ Ní Dídàgbà Lọ́dọ̀ Jèhófà”
23 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Olùgbọ́ Àdúrà”
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ìjọba Tó Máa Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
19 Báwo Lo Ṣe Lè Borí Èrò Òdì?
26 Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ẹnì Kan—Kí Ni Ẹ̀mí Mímọ́?
29 Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Fífi Èdè Fọ̀ Ti Wá?