Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 1, 2010
Ọ̀nà Márùn-ún Téèyàn Lè Gbà Ní Ìtẹ́lọ́rùn
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ǹjẹ́ Ó Ṣeé Ṣe Láti Ní Ìtẹ́lọ́rùn?
4 Ọ̀nà Kìíní. Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Èèyàn, Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Owó àti Ohun Ìní
5 Ọ̀nà Kejì. Má Ṣe Máa Fi Ara Rẹ Wé Àwọn Ẹlòmíì
6 Ọ̀nà Kẹta. Máa Fi Ẹ̀mí Ìmoore Hàn
7 Ọ̀nà Kẹrin. Fi Ọgbọ́n Yan Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ
8 Ọ̀nà Karùn-ún. Fọwọ́ Pàtàkì Mú Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
12 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bá Ọmọ Rẹ Sọ̀rọ̀ Nípa Ìbálòpọ̀
15 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
16 Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Ipa Wo Làwọn Áńgẹ́lì Ń Ní Lórí Wa
18 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
22 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Adẹ́tẹ̀ Kan Rí Ìwòsàn Gbà!
30 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Yóò Jẹ́ Kí O Rí Òun”
31 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
9 Máa Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú bí Jésù Ti Ṣe
27 Ǹjẹ́ Bíbélì Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Orílẹ̀-Èdè Ísírẹ́lì Òde Òní?