Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January 1, 2011
Ọgbà Édẹ́nì Ṣé Ó Wà Lóòótọ́ Àbí Àròsọ Ni?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ṣé Òótọ́ Ni Pé Ọgbà Édẹ́nì Jẹ́ Ilé Ẹ̀dá Èèyàn Ní Ìbẹ̀rẹ̀?
4 Ṣé Òótọ́ Ni Pé Ọgbà Édẹ́nì Wà?
9 Ìdí Tí Ọ̀rọ̀ Nípa Ọgbà Édẹ́nì Fi Kàn Ẹ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
12 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Ọlọ́run?
18 Sún Mọ́ Ọlọ́run—‘Ó Tu Jèhófà Lójú’
19 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
24 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Ó Fara Da Ìjákulẹ̀
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Mọrírì Àwọn Ohun Mímọ́!
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
13 Ǹjẹ́ Ọlọ́run Mọ̀ Pé Ádámù àti Éfà Máa Dẹ́ṣẹ̀?
20 Ǹjẹ́ Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ?
29 Wọ́n Rí Ará Ìlà Oòrùn Éṣíà Kan Ní Ítálì Àtijọ́