Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 1, 2011
Jésù—Ibo Ló Ti Wá? Báwo Ló Ṣe Gbé Ìgbé Ayé Rẹ̀? Kí Nìdí Tó Fi Kú?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
6 Jésù—Báwo Ló Ṣe Gbé Ìgbé Ayé Rẹ̀?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
11 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—“Mo Ti Gbà Gbọ́”
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Ni Ọlọ́run Ní Lọ́kàn fún Ilẹ̀ Ayé?
23 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ìgbà Tí Àwọn Arúgbó Yóò Pa Dà Di Ọ̀dọ́
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ǹjẹ́ Ó Máa Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Dá Wà Tí Ẹ̀rù sì Ń Bà Ẹ́?
26 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
31 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
18 Ìgbẹ́jọ́ Tó Burú Jù Lọ Láyé
32 Àkànṣe Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn