Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 1, 2011
Kí Ló Yẹ Káwọn Ọmọdé Kọ́ Nípa Ọlọ́run?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ṣé Ó Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ọlọ́run?
6 Ta Ló Yẹ Kí Ó Kọ́ Àwọn Ọmọdé Nípa Ọlọ́run?
8 Bí A Ṣe Lè Kọ́ Àwọn Ọmọdé Nípa Ọlọ́run—Àwọn Ọ̀nà Wo Ló Dára Jù Lọ Láti Gbà Kọ́ Wọn?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Máa Bọ̀wọ̀ fún Ọkọ Tàbí Aya Rẹ
13 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ó Rántí Pé “Ekuru Ni Wá”
14 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ìdí Tí Àwọn Èèyàn Fi Fẹ́ràn Dọ́káàsì
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Lo Lè Fi Dá Ẹ̀sìn Tòótọ́ Mọ̀?
18 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
23 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
27 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
24 Ṣé Póòpù Ló “Rọ́pò Pétérù Mímọ́”?
28 Ọjọ́ Ayọ̀ àti Ọjọ́ Ìrètí Ohun Rere