Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 1, 2011
Ta Ló Ń Ṣàkóso Ayé Yìí?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ṣé Ẹnì Kan Ló Wà Nídìí Gbogbo Ìwà Ibi Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Yìí?
7 A Tú Àṣírí Ẹni Àìrí Tó Ń Ṣàkóso Ayé Yìí
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
14 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
15 Sún Mọ́ Ọlọ́run—‘Jèhófà, Ìwọ Mọ̀ Mí’
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ọ̀nà Wo Lo Lè Gbà Sún Mọ́ Ọlọ́run?
24 Lẹ́tà Láti Congo (Kinshasa)
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Wọ́n Fi Ẹ̀sùn Èké Kàn Án!
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
11 “Oríṣi Ohun Ọ̀gbìn Méje” Lára Ohun Ọ̀gbìn Ilẹ̀ Tí Ó Dára Náà
18 Olivétan—Ọ̀dọ́mọdé Onírẹ̀lẹ̀ Tó Túmọ̀ Bíbélì sí Èdè Faransé
21 Ṣé Dandan Ni Kéèyàn Máa San Owó Orí?
26 Ọkùnrin Kan Tí Ó Tẹ́ Ọkàn Jèhófà Lọ́rùn
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fọ́tò: Alain Leprince - La Piscine-musée, Roubaix / Courtesy of the former Bouchard Museum, Paris