ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w11 9/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
w11 9/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ṣé ẹnì kan ló wà nídìí gbogbo ìwà ibi tó ń ṣẹlẹ̀ láyé yìí?

WO OJÚ ÌWÉ 3 SÍ 9.

Kí ni “oríṣi ohun ọ̀gbìn méje” tó fi hàn pé orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ tó dára?

WO OJÚ ÌWÉ 11 SÍ 13.

Kà nípa ìsapá tí atúmọ̀ èdè ọmọ ilẹ̀ Faransé àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ kan ṣe kó tó lè túmọ̀ Bíbélì sí èdè táwọn èèyàn ń sọ.

WO OJÚ ÌWÉ 18 SÍ 20.

Ipa wo ni ẹ̀rí ọkàn Kristẹni kan ń kó tó bá kan ọ̀ràn sísan owó orí?

WO OJÚ ÌWÉ 21 SÍ 23.

Ǹjẹ́ ìwọ náà lè di ẹni tó tẹ́ ọkàn Ọlọ́run lọ́rùn bí Dáfídì ti ṣe?

WO OJÚ ÌWÉ 26 SÍ 29.

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]

Fọ́tò: Alain Leprince - La Piscine-musée, Roubaix/​Courtesy of the former Bouchard Museum, Paris

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́