Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 1, 2011
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìbálòpọ̀?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ǹjẹ́ Ìdáhùn Ìbéèrè Yẹn Ṣe Pàtàkì?
4 Bíbélì Dáhùn Ìbéèrè Mẹ́wàá Nípa Ìbálòpọ̀
8 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Gbé Ìgbé Ayé Wa Ní Ìbámu Pẹ̀lú Àwọn Ìlànà Bíbélì?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
13 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Ẹ̀yin Tọkọtaya, Ẹ Kọ́ Bí Ẹ Ṣe Jọ Máa Jẹ́ Ẹni Tẹ̀mí
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ọ̀nà Wo Ni Àwọn Òfin Ọlọ́run Gbà Ń Ṣe Wá Láǹfààní?
21 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Bí A Ṣe Lè Ṣe Ojúṣe Wa Lọ́dọ̀ Ọlọ́run
29 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Ọlọ́run Gbà Wọ́n Kúrò Nínú Ìléru Oníná!
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
18 Kí Làwọn Bàbá Lè Ṣe Tí Àjọṣe Wọn Pẹ̀lú Ọmọkùnrin Wọn Kò Fi Ní Bà Jẹ́?
22 Ìgbà Wo Ni Wọ́n Pa Jerúsálẹ́mù Àtijọ́ Run?—Àwọn Ẹ̀rí Tá A Rí Nínú Àwọn Wàláà Alámọ̀