Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 1, 2011
Àjálù Ṣé Ọlọ́run Ló Fi Ń Pọ́n Aráyé Lójú?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
4 Àjálù—Kí Nìdí Tó Fi Pọ̀ Tó Bẹ́ẹ̀?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
14 Lẹ́tà Láti Orílẹ̀-Èdè Norway
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Bí O Ṣe Lè Yan Ọ̀rẹ́ Rere
22 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
26 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Mímọ́, Mímọ́, Mímọ́ Ni Jèhófà”
30 Kọ́ Ọmọ Rẹ—A Pè Wọ́n Ní “Àwọn Ọmọ Ààrá”
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
18 Orúkọ Ọlọ́run àti Ìsapá Alfonso de Zamora Láti Túmọ̀ Ìwé Mímọ́ Lọ́nà Tó Péye
23 “Ìgbà Nínífẹ̀ẹ́ àti Ìgbà Kíkórìíra”
27 Mo Fẹ́ Dà Bí Ọmọbìnrin Jẹ́fútà