Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Wa Nípa—Jésù Kristi
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
4 Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Wa Nípa Jésù Kristi
8 Ǹjẹ́ Ó Ṣe Pàtàkì Kí Á Mọ Ìdáhùn Tó Tọ̀nà?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Jọ̀wọ́ Jẹ́ Ká Pa Dà Wá Sílé”
12 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Nìdí Tí Àwọn Kristẹni Fi Ń Ṣe Ìrìbọmi?
23 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Ó Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ̀, Ó Pèsè fún Wọn, Ó sì Lo Ìfaradà
29 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Ta Ló Rán “Ìràwọ̀” Náà?
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Mósè Gba Iṣẹ́ Pàtàkì Kan
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
18 Àwọn Ìwé Ìhìn Rere Ti Àpókírífà—Ǹjẹ́ Ìtàn Jésù Tí Bíbélì Kò Sọ Ni Lóòótọ́?
20 Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ẹnì Kan—Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run?
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ibi tí a ti rí àwọn fọ́tò ojú ìwé 2 àti 3, lókè wá sí ìsàlẹ̀ àti láti ọ̀wọ́ òsì sí ọwọ́ ọ̀tún: © Massimo Pizzotti/age fotostock and Hagia Sophia; © Angelo Cavalli/age fotostock; © Alain Caste/age fotostock; © 2010 SuperStock; Doré ló ṣe àwòrán yìí